Postproverbials in Yoruba (Nigeria)

Curator(s)

Prof. Aderemi Raji-Oyelade

remraj1@gmail.com

University of Ibadan, Ibadan, Nigeria.

Postproverbial: Ibi pẹlẹbẹ ni a ti ń mú ọ̀ọ̀lẹ̀ jẹ; wọ́n fi ewé pọ́n ọn ni.
Translation: It is from the base that one eats a beans pudding; if it is wrapped in leaves.
Proverb: Ibi pẹlẹbẹ ni a ti ń mú ọ̀ọ̀lẹ̀ jẹ.
Translation: It is from the base that one eats a beans pudding.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ìbàjẹ́ ọjọ́ kan, kì í tán láíláí
Translation: A day of defamation and dishonour never ends forever.
Proverb: Ìbàjẹ́ ọjọ́ kan, kì í tán l’ógún ọdún.
Translation: A day of defamation and dishonour never ends in twenty years.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Gàǹbàrí pa Fúlàní, á sun àtìmọ́lé.
Translation: If the Hausa man kills the Fulani, he will be imprisoned.
Proverb: Gàǹbàrí pa Fúlàní, kò lẹ́jọ́ nínú.
Translation: If the Hausa man kills the Fulani, it is not actionable.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ẹyin ni ń di àkùkọ, tí wọn ò bá sèé jẹ.
Translation: The egg becomes the cock, if it is not cooked and eaten.
Proverb: Ẹyin ni ń di àkùkọ.
Translation: The egg becomes the cock.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Èṣú (rú) ṣ’àṣejù, Ọlọ́run lúgọ dè é.
Translation: Satan disrupts and overreaches himself, God waits in ambush for him.
Proverb: Èṣúrú ṣ’àṣejù, ó tẹ́ l’ọ́wọ́ oníyán.
Translation: Water-yam overreaches its own sweetness, it loses flavour and use before the pounded yam vendor.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ẹṣin iwájú, ni yóò gba ipò kíní.
Translation: The leading horse will (surely) take the first position.
Proverb: Ẹṣin iwájú, ni t’ẹ̀yìn ń wò sáré.
Translation: The leading horse is an example to other racers.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ẹni tó jìn sí kòtò, ojú rẹ̀ ló fọ́.
Translation: He who falls into the pit must be blind.
Proverb: Ẹni tó jìn sí kòtò, ó kọ́ ará ìyókù lọ́gbọ́n.
Translation: He who falls into the pit serves as a scapegoat to others.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ẹni tó jìn sí kòtò, ó fẹ́ náwó fún “dókítà” ni.
Translation: He who falls into the pit is billed to spend money for doctors.
Proverb: Ẹni tó jìn sí kòtò, ó kọ́ ará ìyókù lọ́gbọ́n.
Translation: He who falls into the pit serves as a scapegoat to others.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ẹni tó jìn sí kòtò, ó fẹ́ dí kòtò ni
Translation: He who falls into the pit is eager to fill the pit.
Proverb: Ẹni tó jìn sí kòtò, ó kọ́ ará ìyókù lọ́gbọ́n.
Translation: He who falls into the pit serves as a scapegoat to others.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ẹni tó jìn sí kòtò, kò wo ibi tó ń lọ ni.
Translation: He who falls into the pit is probably unconscious of where he’s going.
Proverb: Ẹni tó jìn sí kòtò, ó kọ́ ará ìyókù lọ́gbọ́n.
Translation: He who falls into the pit serves as a scapegoat to others.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more