Postproverbials in Yoruba (Nigeria)

Curator(s)

Prof. Aderemi Raji-Oyelade

remraj1@gmail.com

University of Ibadan, Ibadan, Nigeria.

Postproverbial: : Ẹni tí a bá torí ẹ̀ pa Adìyẹ , orí ni ó ń’ jẹ.
Translation: The person on whose behalf the hen is sacrificed, eats the head.
Proverb: Ẹni tí a bá torí ẹ̀ pa Adìyẹ , iwe ni ó ń’jẹ.
Translation: The person on whose behalf the hen is sacrificed, eats the gizzard.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ẹni tí a bá torí ẹ̀ pa Adìyẹ, gbogbo rẹ̀ ni ń’jẹ.
Translation: The person on whose behalf the hen is sacrificed, eats it all.
Proverb: Ẹni tí a bá torí ẹ̀ pa Adìyẹ , iwe ni ó ń’jẹ.
Translation: The person on whose behalf the hen is sacrificed, eats the gizzard.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ẹnìkan kì í jẹ́ k’ẹ́nu ó fẹ̀.
Translation: No one sups alone and have his mouth torn open.
Proverb: Ẹnìkan kì í jẹ́ kí ilẹ̀ ó fẹ̀.
Translation: No one sups alone and have the earth open wide.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ẹnìkan kì í jẹ́ “Àwa dé”. Ọ̀pọ̀ ènìyàn ní í jẹ́ “jọ̀nmọ́ọ̀” (Jama’a).
Translation: No single man can claim to the saying, “We have arrived”; it is a congregation that is called “Jama’a”.
Proverb: Ẹnìkan kì í jẹ́ “Àwa dé”.
Translation: No single man can claim to the saying, “We have arrived”.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ẹni bá t’ajà ìranù, yí ò gbowó òṣì.
Translation: He who sells vanity shall be paid with misery.
Proverb: Ẹni bá t’ajà èèpẹ̀, yí ò gbowó òkúta.
Translation: He who sells sand shall be paid with stones.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ẹlẹ́nu rírùn, ọ̀tá pákò.
Translation: He-whose-mouth-stinks is enemy of the chewing stick.
Proverb: Ẹlẹ́nu rírùn ló ni àmù ìyá a rẹ̀.
Translation: He-whose-mouth-stinks owns his mother’s drinking pot.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ẹ̀kọ gbóóná gba ọgbọ́n.
Translation: A hot pap requires wisdom.
Proverb: Ẹ̀kọ gbóóná ń fẹ́ sùúrù
Translation: A hot pap needs patience.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Erin kìí fọn, kí ọmọ rẹ̀ fọn; fèrè tán nílẹ̀ ni.
Translation: The baby elephant does not trumpet when its parent trumpets; such when there are not enough horns.
Proverb: Erin kìí fọn, kí ọmọ rẹ̀ fọn.
Translation: The baby elephant does not trumpet when its parent trumpets.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Ebi kì í p’agún d’ọjọ́ alẹ, igún á ṣiṣẹ́ ni.
Translation: Hunger never kills the vulture till dusk, that’s only when the vulture works.
Proverb: Ebi kì í p’agún d’ọjọ́ alẹ́.
Translation: Hunger never kills the vulture till dusk.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more
Postproverbial: Bọmọdé bá ṣubú, a sunkún; bí àgbà bá ṣubú, a dìde.
Translation: When a child stumbles, s/he burst into tears; when the elder falls, s/he gets up.
Proverb: Bọmọdé bá ṣubú a wo iwájú, bí àgbà bá ṣubú, a wẹ̀ yìn wò.
Translation: When a child stumbles, s/he sets his/her eyes on the destination; when an elder falls, s/he takes a backward glance.
Language - Region: Yoruba (Nigeria)
Read more