Ẹni tó jìn sí kòtò, ó kọ́ ará ìyókù lọ́gbọ́n.

Translation: 
He who falls into the pit serves as a scapegoat to others.
Postproverbial: 
Ẹni tó jìn sí kòtò, ojú rẹ̀ ló fọ́.
Translation: 
He who falls into the pit must be blind.
Postproverbial: 
Ẹni tó jìn sí kòtò, ó fẹ́ náwó fún “dókítà” ni.
Translation: 
He who falls into the pit is billed to spend money for doctors.
Postproverbial: 
Ẹni tó jìn sí kòtò, ó fẹ́ dí kòtò ni
Translation: 
He who falls into the pit is eager to fill the pit.
Postproverbial: 
Ẹni tó jìn sí kòtò, kò wo ibi tó ń lọ ni.
Translation: 
He who falls into the pit is probably unconscious of where he’s going.
Language - Region: 
yoruba-nigeria
Label: 
money
doctor
pit